She Ki Ama So Ede Yoruba Nikan Ni Ibi Yi

kolinzo

Well-Known Member
O seun gan, General Saani! Ere Irinajo Si Ile Amerika ni ede Yooba larinrin! O pani ni erin lopo lopo; o pani ni erin arinfeeku! Ogbeni Edi Mofi ni oyaya gan. Asiko ti wa de bayi fun eni ti o ba ni opolo abi ogbon ati y'ohun pada lati se owo (do-do) sinima bii ti Irinajo Si Ile Amerika. Owo (re-mi) tabua be ninu re!
 
Otitio oro gan-an lo sp yen. O ku si owo aweon elere Yoruba aye ode oni.
 
kolinzo

Well-Known Member
Eyin eniyan mi, e ku deedee iwo yi o, e de kuu ipalemo odun keresimesi to nbo lona o.
Mo kan fe polongo 'Egbe Onkawe Ede Yoruba' ni orile-ede Naijiria. Eka 'Egbe Onkowe Odo Orile-Ede Naijiria', ni won nse. E le ye won wo nibiyi: Egbe Onkawe Ede Yoruba.
Eleyi dara lopo lopo. Sugbo aaahn...Yoruba kika mi o danmoran (O ma se o). Lai fa oro gun, nkan be ni saiti yen. Mo ma gbiyanju lati ma kan sibe ni igba gbogbo kin le ko eko ti o ma gbe Yoruba kika me si oke. Jenera Saani, o seun lopolopo.
 
Ogbeni Kolinzo, a ki i dupe ara en o. Ki Oluwa ran e lowo ninu eto iwe kika ni ede Yoruba, Amin o, Jesu Kristi.
 
Top